Discover millions of ebooks, audiobooks, and so much more with a free trial

Only $11.99/month after trial. Cancel anytime.

Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!
Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!
Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!
Ebook335 pages4 hours

Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!

Rating: 0 out of 5 stars

()

Read preview

About this ebook

Awọn Ṣẹrubani kọlu awọn Ẹmbasi Gẹẹsi ati Amẹrika ni Bangkok ni asiko kan na ti wọn si se ibajẹ lọpọlọpọ, sugbọn awọn wo ni wọn se isẹ yi, ati bawo ni a se le dáwọn duro lati mase se bẹẹ mọ?
LanguageYoruba
PublisherTektime
Release dateJan 1, 2024
ISBN9788835465775
Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!
Author

Owen Jones

Author Owen Jones, from Barry, South Wales, came to writing novels relatively recently, although he has been writing all his adult life. He has lived and worked in several countries and travelled in many, many more. He speaks, or has spoken, seven languages fluently and is currently learning Thai, since he lived in Thailand with his Thai wife of ten years. "It has never taken me long to learn a language," he says, "but Thai bears no relationship to any other language I have ever studied before." When asked about his style of writing, he said, "I'm a Celt, and we are Romantic. I believe in reincarnation and lots more besides in that vein. Those beliefs, like 'Do unto another...', and 'What goes round comes around', Fate and Karma are central to my life, so they are reflected in my work'. His first novel, 'Daddy's Hobby' from the series 'Behind The Smile: The Story of Lek, a Bar Girl in Pattaya' has become the classic novel on Pattaya bar girls and has been followed by six sequels. However, his largest collection is 'The Megan Series', twenty-three novelettes on the psychic development of a young teenage girl, the subtitle of which, 'A Spirit Guide, A Ghost Tiger and One Scary Mother!' sums them up nicely. After fifteen years of travelling, Owen and his wife are now back in his home town. He sums up his style as: "I write about what I see... or think I see... or dream... and in the end, it's all the same really..."

Read more from Owen Jones

Related to Òkú Ààrin Gbùngbùn 2

Reviews for Òkú Ààrin Gbùngbùn 2

Rating: 0 out of 5 stars
0 ratings

0 ratings0 reviews

What did you think?

Tap to rate

Review must be at least 10 words

    Book preview

    Òkú Ààrin Gbùngbùn 2 - Owen Jones

    Aṣẹ-lori-ara

    Àṣẹkíkọ © February 21st. 2024 Owen Jones

    Òkú Ààrin Gbùngbùn 2

    Kódà nǹkan tí kò dára le dára nígbàmíràn!

    Lati ọwọ Owen Jones

    Iwé Titẹ nipasẹ

    Megan Publishing Services

    https://meganthemisconception.com

    Ẹtọ Owen Jones lati jẹ ifihàn gẹgẹbi ònkọwé yi ni ó ti fidimúlẹ ni ìbámu pẹlu awọn abala…77 ati 78 ti Copyright Designs and Patents Act 1988. Ẹtọ ọmọlúàbí ti ònkọwé náà ti fidimúlẹ.

    Ninu iwe àròkọ yìí, awọn eniyan ati awọn iṣẹlẹ, yálà wọn jẹ abáyọri èrò ojú-inu ònkọwé tabi ki wọn lò wọn patapata gẹgẹbi àròsọ.  Àwọn ibi kan le wà, sùgbọn àwọn isẹlẹ náà jẹ àròsọ patapata.

    Gbogbo awọn ẹtọ wa ni ipamọ!

    Yi Series

    Òkú Ààrin Gbùngbùn

    Kìí Se Gbogbo Ẹnitó Pa’ra Rẹ Ni Ó Jẹ Ẹlẹsìn

    -

    Òkú Ààrin Gbùngbùn 2

    Kódà nǹkan tí kò dára le dára nígbàmíràn!

    Kàn si mi ni:

    http://facebook.com/angunjones

    http://twitter.com/lekwilliams

    http://owencerijones.com

    Darapọ mọ lẹtairòhin wa fún iwifúnni abẹ’lé

    lóri awọn iwé Owen Jones

    nipa sise àbẹwò sí

    https://meganthemisconception.com

    ÌYÀSỌTỌ

    Mo ya ẹda iwe yi sọtọ fún iyawo mi, Pranom Jones, nitoriti ó fi ayé mi rọ mi lọrùn niwọn ba agbara rẹ - ó ṣe takuntakun nipa rẹ.

    Karma yóò sán an fún olukuluku bakanna.

    ÌDÚPẸ

    Mo fẹ Iati dupẹ lọwọ arakunrin mi, Rhys Jones, fún iranlọwọ imọran ati àbá rẹ, onkọwe ọrẹ mi, Lord David Prosser fún awọn èrò rẹ lori ibora ati imúlọkànle; si Duncan Whitehead fún irànlọwọ rẹ pẹlu awọn ọrọ ologun oju-omi, ati so onkọwe ati ọrẹ mi Eric J. Gates ti ó fún mi laayè lati lo ọpọlọ rẹ.

    ÀWỌN ÌMÍSÍ BẸẸNI-ÌWÉ-SỌ

    Máse gba ohunkohun gbọ nitoripé o ti gbọ ọ,

    Máse gba ohunkohun gbọ nitoripé wọn ti sọ, ó si di àhesọ fún ọpọlọpọ eniyan,

    Máse gba ohunkohun gbọ nitoripé ó jẹ akọsilẹ ninu iwe ẹsìn rẹ,

    Máse gba ohunkohun gbọ nitoripé awọn olukọ ati alagba ti f’àsẹ si,

    Máse gba awọn asa gbọ nitoripéwọn jẹ atọwọdọwọ lati irandiran,

    Sugbọn lẹhin iwòye ati itúpalẹ, ti ohunkohun bá wà ni ibámu pẹlu irònu ti ó si dára fun ànfààni gbogbo eniyan, gbà á ki o si mu u lò.

    Gautama Buddha

    —-

    Ẹmi Nla, ẹniti ohùn rẹ wà lori afẹfẹ, gbọ mi.  Jẹki ndàgbà ninu agbara ti imọ.

    Jẹki n má a wo ìwọ-oòrùn pupa ati pọpù.  Ki awọn ọwọ mi bọwọ fun awọn ohun ti o ti fifun mi.

    Kọ mi ni awọn àsiri ti wọn farasin labẹ ewé ati okuta, gẹgẹbi o ti kọ awọn eniyan ni ọpọlọpọ ọdún to kọjá.

    Jẹki nlo agbara mi, ki i se lati tobi ju arakunrin mi, sugbọn lati ba ọta mi to tobi julọ jà – emi tikarami.

    Jẹki n má a wá siwaju rẹ nigbagbogbo pẹlu ọwọ mimọ ati ọkan mimọ, ati pe bi ọjọ Ayé mi ti nlọ gẹgẹbi iwọoòrùn, Ẹmi mi yóò padà sọdọ rẹ laisi itijú.

    (Gẹgẹbi àdúrà ibilẹ Sioux)

    ÀWỌN ÀKÓÓNÚ

    Ìdúpẹ

    1 Bangkok, Thailand

    2 James Young

    3 London

    4 Asmara

    5 Koh Samui

    6 Awọn Ìgbésẹ ati Ìlànà

    7 Ẹrọ Náà

    8 Nẹtiwọọki Náà

    9 Awọn Àyédèrú Bangkok

    10 Nẹtiwọọki Náà Ngbòòrò

    11 Abala Kejì

    12 Awọn Abala Náà Duro

    13 Dirọpu Náà

    14 Abala Kẹta

    15 Gúsù Thailand

    16 Dabong, Yala

    17 Machang, Yala

    18 Eré Náà tó Ndúró

    19 Ìsàkóso Isẹ Àkànse

    20 Ọrọ Ìparí

    Nipa Ònkọwé

    Tí A Kò Fààyè Gbà – Iṣọri Kini

    1. BANGKOK, THAILAND

    Maikẹli Adamu, osisẹ ijọba onipò alaabọdé ni Ẹmbásì Ijọba Gẹẹsi ni Ọna Wayalẹsi ni Bangkok, fi ọwọ kan si eti òsì rẹ, ó si lu ori tabili diẹdiẹ laarin rẹ ati àtẹlé rẹ Thai, Jẹnni, ẹniti ó njoko si òdikeji rẹ.  Arabirin naa sakiyesi yiyi oju kuro ni igun oju rẹ, ó rẹrin músẹ, ó ti bọtini didúró diẹ tó wà lori ẹrọ ìkọ́ri rẹ, ósi duro ki Maikẹli sọ nnkankan.

    Rákẹti wo niyẹn?  A kò reti awọn alejò loni, àbí a nreti?

    Rárá, kò si ẹni ti mo mọ, Maiki.  Arabirin naa máa ntúra ká ti ó bá ti ku awọn nikan nibi isẹ, gẹgẹbi wọn se wà báyi, tabi nilé wọn ti kò jina si Ẹmbásì náà. Wọn ti nsisẹ papọ fun ọdún meji wọn si ti nsètò lati se igbeyawó ki ọdun naa tó pari.  Arabirin na ọwọ òsì rẹ sita ó fi sinu ọwọ arakunrin naa.

    "Sé ki npe ẹrọ ibanisọrọ lati se àwári nnkan tó nsẹlẹ

    Okunrin naa, rẹrin músẹ, ó di ọwọ rẹ mu, ó sì mi ori padà, iró bilédì rotọ naa di ni léti ninu ọfisi kékeré tó wà lókè naa, nibiti wọn ti nsisẹ lori awọn iwe ibéérè fọọmù ayédèrú físà.

    Bi arabirin naa ti gbiyanjú lati fi ọwọ ọtún rẹ mu ẹrọ ibanisọrọ, okunrin naa wipe,Bẹẹni, jọwọ, arẹwà… sugbọn kò ni ààyè lati pari gbólóhùn naa tabi kó dá ẹrin arabirin naa padà. 

    Ìró nlá sẹlẹ ni oke ibiti wọn wà, eyi ti ó fọn awọn irin kékeké káàkiri to gé wọn lójú, ti nnkankan si fò niwaju wọn niwọn isẹjú àáyá kí ó tó já ọwọ wọn kúrò, ti ó gé tabili si meji, tí ó gé ẹsẹ wọn tó parẹ nilẹ.

    Bi awọn ògúlùtu ti nwọ́lé wọn lori lati oke, ìró nla kan wá lati isàlẹ, ti ó kùn leti wọn bi ẹfọn, ó kọ́kọ́ kọlu awọn ògiri lẹhin wọn, lẹhin naa ó kọlu òrùlé na.  Ti wọn bá wà lááyè, gẹgẹbi awọn diẹ tó wà ninu ile naa, wọn ì bá ti ri àgbá àádọta gálọnù keji to jábọ lati inu ihò kan naa ti ó si mu iná jáde.  Kò nilò ẹkẹta, kò si ẹniti ó wà lááyè ni ti èyiti ó sẹlẹ kẹhin, sugbọn Maiki ati Jẹnni ti wà lọna Ọrun ti wọn si fa ara wọn lọwọ, ti wọn kò si mọ ohun ti ó ti sẹlẹ si wọn ati gbogbo awọn alabasisẹpọ wọn.

    Ṣé awọn ará Amẹrikà gbọn jù wá lọ ni? Olori Ijọba Huw Lloyd, bèèrè lọwọ Minisita Ilẹ Okèèrè rẹ, Richard Wilkinson ni asikò ipadé pàjáwiri ti wọn se ni aago mẹsan àárọ, nnkan bii ogoji iṣẹju lẹhin ti awọn iṣẹlẹ náà ti sẹlẹ.

    Rárá sà, tabi wọn kò tí ì sọ nnkankan sibẹsibẹ, sugbọn mo woye wipé kò yé awọn náà gẹgẹbi kò se yé wa.

    Kíló sẹlẹ si wọn gan an?

    Kò si ẹniti ó nsọ nkankan pàtó, sà, sugbọn ó dàbi wipé wọn mú bárẹlì awọn ẹtù lati ori òrùlé, bí a ti se, lẹhinna wọn ti awakọ ofurufu náà sita, ẹniti ó jẹ ọmọ Amẹrikà tó nsisẹ ni Bangkọki, ti wọn si ju bààlúù náà tó kún fún epo pẹtirolu, lati inu iho náà, eyi tí ó fa ibajẹ pupọpupọ eyi ti a ní.

    O nsọ wipe kò si ẹnikẹni ti o yè ninu iṣẹlẹ náà.

    Ẹru bà mi, ó dà bẹẹ, sà, àyàfi awọn ti wọn soriire ti wọn wà ni ààyè isimi.

    Ju gbogbo rẹ lọ awọn ile iṣẹ ilu òkèèrè mejeeji wọnyi wà nitosi ara wọn? 

    Rárá, ki i se bẹẹ, sà, sugbọn wọn kò jinna sira wọn…Tiwa wà ni Ọnà Wáyálẹsi, tiwọn wà ni ikórita nisàlẹ idojukọ ọna náà, awọn mejeeji ninu Lumpini, ni aarin gbùngbùn Bangkọki.

    Ètò ti kò dara rara niyẹn, abi ki i se bẹẹ? Wọn kàn nwá wàhálà ni, ti o bá bi mi.

    Bẹẹni, sà, sugbọn awọn ile isẹ ilẹ okèèrè yẹn ti wà nibẹ sáájú ìṣẹdá ọkọ ofurufú, sà.

    Oh, Ó yé mi…Njẹ ẹkunrẹrẹ miràn wà bí, Richard?

    "Rárá, sà, a nsisẹ lori rẹ, sugbọn a kò ka Thailand kún ibi ti ó léwu, bẹẹni awọn àdó olóró náà pa awọn eniyan wa lẹsẹkẹsẹ.  Awọn alaṣẹ Thai npa’ná isẹlẹ náà, wọn si ti se àkámọ agbegbe naa, a si ni awọn eniyan ti nbọ lọna, sugbọn yóò tó ọla ki a tó mọ sii nipa isẹlẹ náà.

    Irú àjálù wo niyi, ni ọdun idibo!  Awọn ile isẹ ilu okèèrè ó sunmọra bayẹn to dabi wipé ijambá nduró lati sẹlẹ, abi ki i se bẹẹ?

    "A ti gba awọn ipè diẹ lori ẹrọ ibanisọrọ, sugbọn lati ọdọ awọn ẹgbẹ dìgbòlugi ti wọn kò le sètò nkankan náà ni. Ẹru bà mi ó jọ pé awọn ISIS tabi Al-Qaeda ló wà nidi ọràn yìí.

    Emi kò mọ wipé wọn ni àsepọ ni Thailand.

    Rara, awa náà kò ní, sà, sùgbọn awọn Musulumi alákatakiti wà ni gúsù.  Ó kàn jẹ nǹkan ti a le lérò nisisiyi, sugbọn ó jẹ nǹkan ti o le sẹlẹ ti a ti ni.

    Njẹ o ti sọ èrò yẹn fun awọn ara Amẹrika?

    Rara, sà, sugbọn kò ni yà mi lẹnu ti awọn náà bá ro iru èrò yẹn bakanaa.

    Ó dáa lati se nnkan tí ó tọ, fun mi ni gbogbo iwifunni ti o ba le ri lori awọn Musulumi ni Thailand, ki o si jẹki nmọ gbogbo nnkan ti wọn bá ti nwọlé.  Á á dara ti o ba le fun mi ni awọn nnkan ti mo le kà lẹsẹkẹsẹ nile lálẹ yi.  Jẹki ẹnikan má a sisẹ le lorí, Richard.  Lẹsẹkẹsẹ, sé o gbọ?

    Bẹẹni, sà, Mà á bẹrẹ isẹ lẹsẹkẹsẹ.

    Oh, ó ku nǹkankan ki o tó lọ, mo fẹ se ipàdé pẹlu gbogbo awọn akọsẹmọsẹ ti a ti ní nibiyi ni aago mẹta ọsán yi at M16.

    Ó dáá sà.

    Kọmiṣánnà-Gbogbogbòò ti Ọlọpa Ọba Thai, Ọlọpa Gbogbogbòò Phao Dhanaranjata ti pe ipàdé akọkọ ti rogbodiyàn naa si aago mẹrin-ààbọ ọsán, lẹhin ọgbọn isẹju ti iròhin isẹlẹ náà dé ọdọ rẹ. Awọn ẹlẹri, ti ó pẹlu awọn ọlọpa ti wọn wà nibi isẹ, ati awọn osisẹ asoju ilẹ okèèrè ni agbegbe náà ati awọn olùgbé fi akoko isẹlẹ náà ni ile asoju ilẹ okèèrè Gẹẹsi si aago mẹrin ku isẹju mejila ọsán, ti ekeji sẹlẹ ni ile isẹ asoju ilẹ òkèèrè Amẹrika ni isẹju mẹrin lẹhin náà.

    Awọn Ile isẹ Panápaná jábọ wipe awọn ti kápá iná awọn ile náà, sugbọn wọn sì njó, bẹẹni agbègbè náà gbóná ju ibiti eniyan le wọnu rẹ lọ, kì í se wipé wọn ni àsẹ lati wọ’bẹ nitoripe ori ilẹ òkèèrè ni, ni ti ọrọ alásẹ.

    Awọn ọlọpa jábọ wipe awọn ti pààlà yipo agbègbè náà kí ìbújáde miràn máse sẹlẹ, bẹẹni Ọfisi Thai Ilẹ Òkèèrè jábọ wipe awọn ti bèèrè fun àtòjọ gbogbo awọn ara ilu Thai ti wọn ti sisẹ ninu ile isẹ ile òkèèrè, ti wọn si ti wa lárọwọtó lati pèsè awọn ijábọ ti wọn ni lati Bangkok si awọn ijọba Gẹẹsi ati ti Amẹrika.

    Kọmiṣánnà-Gbogbogbòò náà fi dánilójú wipe gbogbo ohun tó yẹ lati se ni wọn nse, ati wipé awọn ijọba ilẹ òkèèrè yóò fi atòjọ awọn òsisẹ ránsẹ ki ọjọ yẹn tó pari. Ó mọ nipa irirí wipé wọn yóò fẹ kí òun se ìwádìí t’òun si awọn ikọlù sẹrùbani náà, sugbọn awọn Gẹẹsì ati Amẹrikà yóò fẹ òminira lati se iwádìí tiwọn bakannaa.

    Kò lòdi si wọn niwọnigbati awọn eniyan wọn bà mọ wipé abẹ isakóso òun ni wọn wà, ti wọn si fun ni itẹriba ti ó yẹ. Igbésẹ rẹ àkọkọ ni ki ó sàwári ẹni ti ó ni bààlúù náà, nitorina ó pàsẹ fun ọkan lara awọn igbakeji rẹ lati sisẹ lori iyẹn, nigbati òun nsisẹ lori iwe iròhin.

    Ó jẹ ohun àkọkọ, nitori awọn ẹgbẹ oniròhin Ṣanẹli Ologun 7 ti ndúró nita ti wọn si nfẹ ki wọn sọ nnkankan fún wọn kiakia, botilẹjẹ wipé wọn gbọdọ se dáadáa, nitoripé igbà akọkọ niyi ni itage agbayé, ó si gbọdọ s’àfihàn wipé oun jáfáfá òun si kún ojú osùwọn.

    Gẹgẹbi ó ti sẹlẹ, ijabọ akọkọ ti iròhin náà ti wà lori ẹrọ mohunmáwòrán.  Awọn ẹlẹri kan ti ya fọtọ bààlúù náà tí ó nrábàbà lóri Ile isẹ òkèèrè Gẹẹsi ti wọn si tẹle titi di igbati ó se jàmbá náà, nitorina pipè lori ẹrọ ibanisọrọ nikan ló nilò lati tọpinpin àwọn ti wọn ni bààlúù ná latibi àmi-ìpè ti ó wà lara ẹgbẹ ọkọ ofurufu náà. Awọn to ni bààlúù náà ni ile isẹ ti a npe ni Bangkok Aerial Photography Limited, tí wọn má a nháya awọn bààlúù pẹlu awọn awakọ ofurufu lati ya aworán lofurufu. Awọn eniyan kan ngbiyanju lati ta awọn fídíò wọn, nigbati awọn miran ti sẹsẹ gbe wọn sori Yútubu ki gbogbo eniyan le ri ki wọn si se ẹda rẹ, eyi ti pupọ awọn ile-isẹ Mohunmáworan se lai lo làákàyè.

    Gbolohun ati àrọwà ọgá ọlọpa náà fún iwifúnni wà ni ipari fidiò náà.

    Ẹru ba awọn eniyan Thailand inu si bi wọn gidigidi wipe iru nnkan buburu náà le sẹlẹ lori ilẹ Thai, tabi ni awọn ile isẹ ilu òkèèrè ni Thailand.

    Awọn okunrin mẹrin náà joko ni igun tabili nla ninu Ọfisi Kabinẹti Yàrá Ifitóniléti ‘A’, eyi ti ìkékúrú rẹ jẹ COBRA, ni Nọmba 10 nibiti Akọwe Ilẹ Òkèèrè, Akọwe fun Ààbò, Toby Smythe, Ọgagun Òsisẹ Idábòbò, Marshall Sir Roderic Jones, at Ọga ti MI6, Sir Arthur Tobin.  Richard Wilkinson pin tákàdá iwe kọọkan fun ẹnikọọkan ti ó si fi ẹyọkan sibi ìjoko tó sófo ti ori tabili fun P.M. ẹniti yóò wọlé láìpẹ.

    Oloye, njẹ òótọ ni wipe ọkan lara awọn eniyan rẹ ni Ile isẹ ilẹ òkèèrè ni Michael Adams?

    Bẹẹni, òtitọ ni, Toby, sé o mọ ọ ni?

    Ki i se wipe mo mọ ọ dáadáa, sugbọn a ni lati pade fun sise kan… ni nnkan bii igba meji. Mo ni iwoye wipe eniyan dáadáa ni.  Mo bá ọ yọ, alàgbà.

    Ẹ se, Toby.  Awọn eniyan sọ wipe ó dáa.  Sá à kọwé bèèrè àyè isimi lati gbeyawó…Ọmọbirin kan ninu ọfisi, ara Thai, ti ó rẹwa ni gbogbo ọna…

    Ẹ dákẹ, ẹyin èèyàn, Akọwe Ile isẹ Òkèère fi oríke-ìka rẹ lu tabili jẹẹjẹẹ.Ẹ sé.  Mo tọrọ gáfárà fun àìsí ẹrọ, ẹyin èèyàn, sugbọn ohun ti a ni niyẹn ni akoko yi.  Sibẹsibẹ iwifunni pupọ nbọ nigbagbogbo.  Bi akoko se yàtọ si kò sèránwọ…

    Bẹẹni, iyẹn ọkan lara awọn kókó iwifunni ti ẹ o fi sinu tákàdá iwe yi, wọn fi wakati meje sáájú wa, ni adari MI6 sọ jade."Gbogbo awọn nnkan wọnyi ló ti wà lori ẹrọ mohunmaworan ni ọpọlọpọ igba lati igba ti ó ti sẹlẹ.

    Bẹẹni, Má binu, Arthur, sugbọn gbogbo awọn eniyan wa ni wọn pa ninu ikọlu náà.  Gbogbo eniyan ló parẹ nile isẹ òkèèrè wa ati awọn Yanki’.

    Lojiji, awọn ilẹkun si ni igun yàrá náà lọhùn-ún P.M. si wọlé pẹlú awọn àtẹlé rẹ.

    Ó dáa, ẹ le má a lọ nisisiyi, ó sọ fún wọn.Sọ fún gbogbo awọn tó kàn wipé ki wọn máse yọ wa lẹnu fún ohunkóhun.  Ìpàdé yi se kókó.

    Ó wò wọn bi awọn òsisẹ rẹ se kuro ninu yàrá náà.

    Ó dáa, ẹyin èèyàn, ẹ jẹká bẹrẹ isẹ. Richard, iwọ lo sètò ipadé yi, kilódé tí ó kò bẹrẹ?  Ó sún iwe iwifunni tirẹ si ọdọ rẹ, ó ka awọn ilà iwinfunni diẹ, ó si láti wo o si i, nigbati Akọwe Ilẹ Òkèèrè tún ohùn rẹ se.Ó gbé oju soke lati wo awọn ti ó nsọ ọ, ó si ti tákàdá ti kò wulò náà kúrò lọdọ rẹ lẹẹkansi.

    "Bẹẹni, ó dáa, ẹyin èèyàn, eyi jẹ ipade ibẹrẹ lati sakojọ iwọnba ohun ti a ni ki a le sètò igbesẹ.  A ti seto fun ikọ MI6, ọlọpa ati awọn ọtẹlẹmúyẹ ologun lati wọ’kọ ofurufu lọ si Bangkok nirọlẹ yi pẹlu ẹgbẹ awọn eniyan diẹ lati rọpo awọn osisẹ ile-isẹ ilẹ òkèèrè.  Ki á má wulẹ sọ wipé a kọwe bèèrè fún awọn físà tó yẹ ati anfààni iselu bi ẹnipé gbogbo wọn ni òsisẹ ile-isẹ ilẹ òkèèrè, wọn si buwọlu gbogbo iwe isẹ náà.

    Awọn alásẹ Thai nfọwọsowọpọ wọn si ti fún wọn ni ààyè ọfisi ninu ile kan ti kò jinna si isalẹ ọna náà ti VFS Global nlò, ile-isẹ ajọse ijọba ti ó nsisẹ lori awọn iwe ibèèrè fún físà lati ibẹrẹ.  Wọn kò fojusun ile yi tabi ki wọn bàájẹ, sugbọn pupọ awọn osisẹ naa ni ara Thai… 

    Mo tọrọ gáfárà lati jarọ lẹnu, Dicky, se o ndábàá wipe awọn tó sọ’sẹ yi fi ile yẹn silẹ nitoripe pupọ awọn osisẹ naa jẹ ara Thai? Ọga naa bèèrè.

    Kì í se ni ikorita yi, Arthur.  A rò pe wọn fojúsun awọn ile-isẹ ilẹ òkèèrè mejeji funrawọn ni, sugbọn ó yẹ lati fi sọkan. Láìse àníàní, a ni awọn eniyan ti wọn ti nse àyẹwo aworán isẹlẹ náà, ati pé awọn àdó olóró náà dabi àádọta-le-nigba awọn àgbá epo – àtọwọdá (IEDs).  Èkini lori ile-isẹ kọọkan dabi i wipe ó kún fún awọn ẹtu giga, ekeji lori ile-isẹ kún fún epo okiteni-giga.  Nnkankan náà ló sẹlẹ lori ile-isẹ ilẹ òkèèrè Amẹrika nigbati bààlúù náà jálulẹ latibi ihò èyiti IED se okùnfà rẹ…

    Sé òrùlé náà kò lágbara ni?

    Wọn ti fun lágbara, Toby, sugbọn mà á fẹ ki gbogbo yin wo fidio yi. Bayi, jọwọ, ló bá kọjusi ọtẹlẹmuyẹ ologun ti o wa nidi fidio náà."Awọn osisẹ ẹrọ ti jẹki aworan náà darasi, bi ó ti wa ni ipa wọn, sugbọn…mímugbòòrò si bayi ni awọn wahala tirẹ.

    "Ó dáa, nibiyi wà á rí bààlúù náà ti ó nfò lori ile isẹ òkèèrè wa, akọkọ tó kọkọ kọlù, lẹhinna wà á ri ohun tó dabi awọn ọkunrin meji ti wọn nyi àgbá jade lẹgbẹ ilẹkun.A ti siro wipe bààlúù naa ga laarin àádọ́jọ. si àádọ́san ẹsẹ bàtà  loke ile naa ni ikorita yi. Bayi wò ó  dáadáa laarin ẹsẹ bàtà mẹwàá si mẹẹdógún àgbá naa ti wọn ti yi si ẹgbẹ, ti tún ara rẹ se. Igbékalẹ naa ti dìmọra! Se akiyesi abẹ naa…wà á ri awọn igbekalẹ tó dabi ori ọfà

    "Aadọta-le-nigba àgbá ti wọn kún fún awọn ẹtu le tó àádọta-lé-nigba kilos, sugbọn àròpọ iwúwo naa lati jẹki ó wá si isalẹ, le jẹki àgbá naa wúwo tó ọọdunrún kilos. Ọọdúnrún kilo ni inṣhin kan le ni ipa…ẹru ba mi, nkò mọ ohun bi eyi yóò ti pọ tó lẹhin tó bá ti jábọ lati aadọjọ ẹsẹ bátà loke si isalẹ, sugbọn nkò mọ iru orulé tó le gba irú àjálù báyẹn dúro, dájúdájú tiwa tabi ti awọn Amẹrika kò le gbà á dúro.

    "Se awọn sẹrubani naa mọ iyẹn tabi wọn kàn gbiyànjú ohun ija wọn ni?  Talo mọ?  Njẹ ẹnikẹni sọ iwifunni ifura nipa orule naa fún wọn? A kò mọ? Dajudaju awọn okunrin ti wọn nsetọju yóò ti mọ nipa ipo òrùlé pàápàá julọ awọn òrùlé naa. Ó DÁA, yii.  Ni kete ti wọn ju IED naa silẹ ni bààlúù naa sún diẹ, lẹhinna, ó padà lẹhin ìró kini, ó ju àgbá epo keji silẹ ó si fò lọ si Ile isẹ Òkèèrè Amẹrika ti kò ju nkan bii isẹju kan sibẹ yẹn.

    "Wọn ju IED, sún kúrò ni ọgbà tó wa lẹhin lati yẹra fún ibújáde lẹẹkansi, wọn si ju nnkan sita bii àgbá naa ti nbú jáde. Ó di afihàn nigbòóse wipé ẹni naa jẹ awakọ ara Amẹrika tó ti nwa bààlúù fún awọn sẹrùbani fún ile isẹ ibiti wọn ti háyà rẹ.

    "Wọn á ti yinbọn fún lati ìpàkọ, nitorina wọn á ti wá arọpò awakọ ofurufu, ó kéré tan ọkan-ò-jọkan, nitori ọkọ naa pada si òrùlé tó ti já ó si wọnu iho ti IED naa dálu tó múná jáde gẹgẹbi isẹ wa.

    Eyi mu mi ránti ti 9/11 gẹgẹbi o ti dá mi loju wipe ẹ mọ nipa rẹ.

    O sé, ó sọ fún osisẹ-ẹrọ naa,"o le má a lọ bayi.

    Ó dáa, ẹyin èèyàn, gbogbo nnkan ti mo ni niyẹn.

    O sé, Richard, ni P.M. sọ.Njẹ ẹnikan ni nnkankan lati fikun? Atamátàsé ni, kò si àsìse. Mo woye wipe awọn Amẹrika gan an ni wọn fojúsùn, sugbọn a sunmọra pẹkipẹki tó jẹ wipe iyalẹnu lo jẹ fún awọn rádaràda yi.  Òkò kan pa ẹyẹ meji, eh?  Tó tun jẹ eyi ti wọn háyà, botilẹjẹpe kò si ẹniti ó má a sanwó rẹ. Oh, wọn ya tabi jale rẹ.

    Ó fẹrẹ jẹ pe hiháyà ni, Olori Ijọba. A kò mọ ohunkohun, a kò ni ẹnikẹni nibẹ àyàfi akọròhin, nitorina a gbẹkẹle awọn alasẹ Thai ati awọn akọròhin fún imọ wa ti abẹlé. Awọn Kọnsu ni Chiang Mai ati Pattaya ni wọn ti sọ fun ki wọn tete lọ si ojúkò wọn, sugbọn agbalagba niwọn wọn ko si ni idanilẹkọ fun iru isẹ yi, sibẹsibẹ wọn si le seranwọ nipa sisaáyan awọn físà. Wọn gbọdọ dé’bẹ laarin wakati mẹta, ni Richard sọ, tó si nsayẹwò aago rẹ pẹlu aago tó wà lóri pẹpẹ.

    Njẹ ẹnikan ni nkankan lati sọ bí? Olóyè? ó kọju si olóri MI6.

    "Rárá, kò si iroyin kan gbòógì, awọn osisẹ wa mẹtẹta lo wa lẹnu isẹ. Mo sá à le sọ wipe a kò ni ifura ikọlu sẹrubani laipẹ.Thailand jẹ orilẹ-ede alafia ayafi awọn isoro abẹlé pẹlu awọn Ẹlẹyamẹya Musulumi ni gusu pẹlu Malaysia.  Ó jẹ ibèèrè Áíríshi wọn, sugbọn wọn se e ni ti abẹlé.  Yatọ si iyẹn, Thailand jẹ apata pataki laarin awọn orilẹ-ede iha ila-oòrùn Kọmunisiti bii Laos, Cambodia ati Vietnam ati ijọba ni Myanmar, er, Burma atijọ. 

    Kò si awọn nkan tó kàn wá lati igbà ọdun Alaadọrin ati Vietnam.  Ẹru ba wa pupọ nitoripe a wà ninu ewu.  Ó tumọ si wipe a nilati sàgbéyẹwò awọn ile isẹ wa nilẹ okèèrè bakanna, ki ó má ba a di ajakalẹ-arùn.  Ẹrù ba mi wipe abajade awọn ikọlu wọnyi le jasi ọpọlọpọ ikọlu miran latọwọ ẹgbẹ kan naa, tabi awọn awòse bọmbu asekúpani. 

    A fura si awọn Al-Qaeda tabi ISIS gẹgẹbi awọn tó wà nidi ijamba yi.

    Awọn èèyàn mi ori wọn wọn si wo tákàdá pẹlu akọsilẹ wọn tó wà niwaju wọn. 

    "Ó dabi ẹnipe gbogbo eniyan lo gbà bẹẹ, Arthur, bẹẹni. Ó dáa, mo ni iroyin kekere kan lati fikun.  Mo sẹsẹ sọrọ tan pẹlu Aarẹ Amẹrika, ó si wipe awọn naa kò mọ nnkankan… sọrọ si iyẹn. Ó dáa, iyẹn bayẹn fún igba kan na, ẹyin èèyàn, ẹ sé fún wiwá yín. Ẹ mọ wipe a ko le mase ma a sọ bi nkan yi se se pataki si – o se pataki gidigidi, paapaa julọ latari awọn ikọlu tó le wáye ni awọn ile isẹ ilẹ òkèèrè miran, gẹgẹbi Olóyè ti tọkasi.

    Richard, wà á fi iwifunni tuntun ransẹ bi ó bá ti ndé, abi o kò ni se bẹẹ?

    Bẹẹni, sà, ni kete ti mo bá ti tẹẹ sinu iwé tán.

    "Okunrin dáadáa, Mo fẹ ri gbogbo yin pada sibi yi ni aago mẹta Ioni, ẹyin èèyàn, ẹ jẹki a wo bi a se maa tètè sisẹ si lori eyi. Sọ fun ẹnikẹni ti o ba nilati sọ fun ki o ba le ni aseyọri. Ma a wa Iarọwọto fun igbaninimọràn loni ni ọfisi mi. Mo ti fagile gbogbo awọn ipade mi. Nko ni sọ wipe ki gbogbo yin se bẹẹ, sugbọn isẹ yi jẹ akọkọse.

    Óyá, ẹ jẹ ká bẹrẹ isẹ.

    Awọn ọkunrin marun kan naa mu ijoko wọn lori tabili kan naa ni aago mẹta lọsan ọjọ yẹn.  Akọwe Ilẹ Òkèèrè lo se alaga ipade náà.

    "Ó dáa, ẹyin èèyàn, nitori iru  èniyan ti ẹ jẹ, ati nitoripe a ti nsisẹ papọ lati àárọ ti ipade yi ti bẹrẹ, mo mọ wipe pupọ yin ni o ni nnkan lati sọ bayi, nitorina mà á lọ káàkiri tabili naa ni ọkọọkan.

    Arthur, mo lero wipe wà á fẹ lati kọkọ lọ, abi ki i se bẹẹ?

    Bẹẹni, Dicky, ẹ sé… Ókunrin naa rẹrin músẹ bi ina se yara tàn lori ẹrọ alágbèéká rẹ tó wa lori tabili niwaju rẹ dá ọrọ mọ lẹnu.Mo tọrọ gáfárà, PM, eyi bamu.  Ó ka ifiransẹ sinu, o si salaye,Ọkan lara okunrin agba Ile-isẹ naa, James Young, sẹsẹ wọ’kọ ofurufu 1455 Bààlúù ti Gẹẹsi tó nlọ si Bangkok.  Yóò dé‘bẹ ni 09.10 aago tiwọn lọla, iyẹn 02-10 nibiyi.

    O kare, Arthur, ni Olori Ijọba wi,jọwọ tẹsiwaju.

    "Ó dáa, ki nsọ otitọ, saà, awọn iroyin tókù kò dára pupọ. A ni awọn osisẹ ni gbogbo awọn ile-isẹ orilẹ-ede ilẹ òkèèrè layika, mo si le jẹki wọn wá si Bangkok laisi wahala, sugbọn kò si ọkankan ninu wọn to gbọ ede ibilẹ Thai.  Ó dabi ẹni pe Thai nikan ni ede kansoso ti wọn nsọ nibẹ -  – awọn Thais nikan ni wọn nsọ ọ… o dabi i Wẹlsh.

    "Lao naa farajọ-ọ, sugbọn ó yatọ, bi i Bretagne se ri si Wẹlsh.  Ni kukuru, a ti ni ipin mẹrin ni Laos, Kambodia, Myanmar ati Malaysia, gbogbo awọn orilẹ-ede layika sugbọn ko si ọkankan ninu wọn to wulo fun wa rara.  Young ko le sọ ede Thai, sugbọn ó wulo.  A ngbiyanju lati se nnkankan pẹlu Ọtẹlẹmuyẹ Ológun, sugbọn kò ti i dá wa loju… wọn sábà máa nsere idaraya pẹlu awọn jagunjagun Thai tabi ki wọn kọ wọn ni bi wọn se nlo awọn ohun ijà Gẹẹsi.

    Boya Toby le là wá lọyẹ siwaju si lori eleyi.

    Ẹru kò bami, ẹyin èèyàn, ki i se ni akókò yi gan an. Mo le sẹjẹri wipe a ti sọ fun gbogbo ẹka awọn jagunjagun pẹlupẹlu Awọn Ipin Pataki, pe a nwá awọn onsọrọ Thai, pẹlupẹlu ede abẹlé, sugbọn nko lero wipe a má a gbọ siwaju si i nipa rẹ loni…Má bìínu.

    Ó dáa, ẹ sé, Toby. Roddy?

    "Mo le sejẹri ohun ti Toby sẹsẹ sọ tan, mo si ni ẹkunrẹrẹ irinajo awọn arọpò osisẹ si agbegbe náà.  Bààlúù Merlin kan lati RAF Benson, yóò lọ

    Enjoying the preview?
    Page 1 of 1